Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 7:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si yá ere ẹgbọ̀rọ malu ni ijọ wọnni, nwọn si rubọ si ere na, nwọn si nyọ̀ ninu iṣẹ ọwọ́ ara wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 7

Wo Iṣe Apo 7:41 ni o tọ