Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 7:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose na yi ti nwọn kọ̀, wipe, Tali o fi ọ jẹ olori ati onidajọ? on na li Ọlọrun rán lọ lati ọwọ́ angẹli, ti o farahàn a ni igbẹ́, lati ṣe olori ati oludande.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 7

Wo Iṣe Apo 7:35 ni o tọ