Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 4:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki eyi ki o yé gbogbo nyin ati gbogbo enia Israeli pe, li orukọ Jesu Kristi ti Nasareti, ti ẹnyin kàn mọ agbelebu, ti Ọlọrun gbé dide kuro ninu okú, nipa rẹ̀ li ọkunrin yi fi duro niwaju nyin ni dida ara ṣaṣa.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:10 ni o tọ