Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 3:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Peteru si ri i, o dahùn wi fun awọn enia pe, Ẹnyin enia Israeli, ẽṣe ti ha fi nṣe nyin si eyi? tabi ẽṣe ti ẹnyin fi tẹjumọ́ wa, bi ẹnipe agbara tabi iwa-mimọ́ wa li awa fi ṣe ti ọkunrin yi fi nrin?

Ka pipe ipin Iṣe Apo 3

Wo Iṣe Apo 3:12 ni o tọ