Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 27:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn balogun ọrún nfẹ gbà Paulu là, o kọ̀ ero wọn; o si paṣẹ fun awọn ti o le wẹ̀ ki nwọn ki o kọ́ bọ si okun lọ si ilẹ,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 27

Wo Iṣe Apo 27:43 ni o tọ