Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 27:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nitori ebute na kò rọrùn lati lo akoko otutu nibẹ̀, awọn pipọ si damọran pe, ki a lọ kuro nibẹ̀, bi nwọn ó le làkàka de Fenike lati lo akoko otutu, ti iṣe ebute Krete ti o kọju si òsi ìwọ õrùn, ati ọtún ìwọ õrùn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 27

Wo Iṣe Apo 27:12 ni o tọ