Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 27:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi a si ti pinnu rẹ̀ pe ki a wọ̀ ọkọ lọ si Itali, nwọn fi Paulu, ati awọn ondè miran kan pẹlu, le balogun ọrún kan lọwọ, ti a npè ni Juliu, ti ẹgbẹ ọmọ-ogun Augustu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 27

Wo Iṣe Apo 27:1 ni o tọ