Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 26:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi mo si ti ri iranlọwọ gbà lọdọ Ọlọrun, mo duro titi o fi di oni, mo njẹri fun ati ewe ati àgba, emi kò sọ ohun miran bikoṣe ohun ti awọn woli ati Mose ti wipe yio ṣẹ:

Ka pipe ipin Iṣe Apo 26

Wo Iṣe Apo 26:22 ni o tọ