Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 26:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn dide, ki o si fi ẹsẹ rẹ tẹlẹ: nitori eyi ni mo ṣe farahàn ọ lati yàn ọ ni iranṣẹ ati ẹlẹri, fun ohun wọnni ti iwọ ti ri, ati ohun wọnni ti emi ó fi ara hàn fun ọ;

Ka pipe ipin Iṣe Apo 26

Wo Iṣe Apo 26:16 ni o tọ