Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 26:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati gbogbo wa si ṣubu lulẹ, mo gbọ́ ohùn ti nfọ̀ si mi ni ède Heberu pe, Saulu, Saulu, ẽṣe ti iwọ fi nṣe inunibini si mi? Ohun irora ni fun ọ lati tapá si ẹgún.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 26

Wo Iṣe Apo 26:14 ni o tọ