Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 24:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o si ti nsọ asọye nipa ti ododo ati airekọja ati idajọ ti mbọ̀, ẹ̀ru ba Feliksi, o dahùn wipe, Mã lọ nisisiyi na; nigbati mo ba si ni akokò ti o wọ̀, emi o ranṣẹ pè ọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 24

Wo Iṣe Apo 24:25 ni o tọ