Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 23:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati iyapa si di nla, ti olori ogun bẹ̀ru ki Paulu ki o má bà di fifaya lọwọ wọn, o paṣẹ pe ki awọn ọmọ-ogun sọkalẹ lọ lati fi ipá mu u kuro lãrin wọn, ki nwọn si mu u wá sinu ile-olodi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 23

Wo Iṣe Apo 23:10 ni o tọ