Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 23:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI Paulu si tẹjumọ igbimọ, o ni, Ará, emi ti nfi gbogbo ẹri-ọkàn rere lò aiye mi niwaju Ọlọrun titi fi di oni yi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 23

Wo Iṣe Apo 23:1 ni o tọ