Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 21:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awa si ti ri Kipru li òkere, ti awa fi i si ọwọ́ òsi, awa gbé ori ọkọ̀ le Siria, a si gúnlẹ ni Tire: nitori nibẹ̀ li ọkọ̀ yio gbé kó ẹrù silẹ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 21

Wo Iṣe Apo 21:3 ni o tọ