Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 21:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si gbọ́, nwọn yin Ọlọrun logo, nwọn si wi fun u pe, Arakunrin, iwọ ri iye ẹgbẹgbẹrun ninu awọn Ju ti o gbagbọ, gbogbo nwọn li o si ni itara fun ofin.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 21

Wo Iṣe Apo 21:20 ni o tọ