Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 2:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si nfi ọkàn kan duro li ojojumọ́ ninu tẹmpili ati ni bibu akara ni ile, nwọn nfi inu didùn ati ọkàn kan jẹ onjẹ wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 2

Wo Iṣe Apo 2:46 ni o tọ