Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 2:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ki gbogbo ile Israeli ki o mọ̀ dajudaju pe, Ọlọrun ti fi Jesu na, ti ẹnyin kàn mọ agbelebu, jẹ Oluwa ati Kristi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 2

Wo Iṣe Apo 2:36 ni o tọ