Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun wipe, Yio si ṣe ni ikẹhin ọjọ, Emi o tú ninu Ẹmí mi jade sara enia gbogbo: ati awọn ọmọ nyin-ọkunrin ati awọn ọmọ nyin obinrin yio ma sọtẹlẹ, awọn ọdọmọkunrin nyin yio si ma ri iran, awọn arugbo nyin yio si ma lá alá:

Ka pipe ipin Iṣe Apo 2

Wo Iṣe Apo 2:17 ni o tọ