Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 19:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si wọ̀ inu sinagogu lọ, o fi igboiya sọ̀rọ li oṣù mẹta, o nfi ọ̀rọ̀ we ọ̀rọ̀, o si nyi wọn lọkan pada si nkan ti iṣe ti ijọba Ọlọrun.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 19

Wo Iṣe Apo 19:8 ni o tọ