Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 19:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Paulu si wipe, Nitõtọ, ni Johanu fi baptismu ti ironupiwada baptisi, o nwi fun awọn enia pe, ki nwọn ki o gbà ẹniti mbọ̀ lẹhin on gbọ, eyini ni Kristi Jesu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 19

Wo Iṣe Apo 19:4 ni o tọ