Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 19:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn Ju kan alarinkiri, alẹmi-èṣu-jade, dawọle e li adabọwọ ara wọn, lati pè orukọ Jesu Oluwa si awọn ti o li ẹmi buburu, wipe, Awa fi orukọ Jesu ti Paulu nwasu fi nyin bu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 19

Wo Iṣe Apo 19:13 ni o tọ