Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 18:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si gbé ọjọ diẹ nibẹ̀, o lọ, o si kọja ni ilẹ Galatia on Frigia lẹsẹsẹ, o nmu gbogbo awọn ọmọ-ẹhin li ọkàn le.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 18

Wo Iṣe Apo 18:23 ni o tọ