Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 18:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn Hellene si mu Sostene, olori sinagogu, nwọn si lù u niwaju itẹ idajọ. Gallioni kò si ṣú si nkan wọnyi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 18

Wo Iṣe Apo 18:17 ni o tọ