Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 17:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn ti gbọ́ ti ajinde okú, awọn miran nṣẹ̀fẹ: ṣugbọn awọn miran wipe, Awa o tún nkan yi gbọ́ li ẹnu rẹ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 17

Wo Iṣe Apo 17:32 ni o tọ