Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 17:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ti fi ẹ̀jẹ kanna da gbogbo orilẹ-ede lati tẹ̀do si oju agbaiye, o si ti pinnu akokò ti a yàn tẹlẹ, ati àla ibugbe wọn;

Ka pipe ipin Iṣe Apo 17

Wo Iṣe Apo 17:26 ni o tọ