Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 16:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojiji iṣẹlẹ nla si ṣẹ̀, tobẹ̃ ti ipilẹ ile tubu mi titi: lọgan gbogbo ilẹkun si ṣí, ìde gbogbo wọn si tu silẹ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 16

Wo Iṣe Apo 16:26 ni o tọ