Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 16:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si ti ri iran na, lọgán awa mura lati lọ si Makedonia, a si gbà pe, Oluwa ti pè wa lati wasu ihinrere fun wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 16

Wo Iṣe Apo 16:10 ni o tọ