Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 14:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si nwipe, Ará, ẽṣe ti ẹnyin fi nṣe nkan wọnyi? Enia oniru ìwa kanna bi ẹnyin li awa pẹlu ti a nwasu ihinrere fun nyin, ki ẹnyin ki o yipada kuro ninu ohun asan wọnyi si Ọlọrun alãye, ti o da ọrun on aiye, ati okun, ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu wọn:

Ka pipe ipin Iṣe Apo 14

Wo Iṣe Apo 14:15 ni o tọ