Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 13:30-32 Yorùbá Bibeli (YCE)

30. Ṣugbọn Ọlọrun jí i dide kuro ninu okú:

31. O si farahàn li ọjọ pipọ fun awọn ti o ba a gòke lati Galili wá si Jerusalemu, awọn ti iṣe ẹlẹri rẹ̀ nisisiyi fun awọn enia.

32. Awa si mu ihinrere wá fun nyin, ti ileri tí a ti ṣe fun awọn baba,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 13