Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 13:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi Johanu si ti nlà ipa tirẹ̀ já, o ni, Tali ẹnyin ṣebi emi iṣe? Emi kì iṣe on. Ṣugbọn ẹ kiyesi i, ẹnikan mbọ̀ lẹhin mi, bata ẹsẹ ẹniti emi kò to itú.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 13

Wo Iṣe Apo 13:25 ni o tọ