Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 11:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AWỌN aposteli ati awọn arakunrin ti o wà ni Judea si gbọ́ pe awọn Keferi pẹlu ti gba ọ̀rọ Ọlọrun.

2. Nigbati Peteru si gòke wá si Jerusalemu, awọn ti ikọla mba a sọ,

3. Wipe, Iwọ wọle tọ̀ awọn enia alaikọlà lọ, o si ba wọn jẹun.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 11