Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 10:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni mo si ti ranṣẹ si ọ lojukanna, iwọ si ṣeun ti o fi wá. Gbogbo wa pé niwaju Ọlọrun nisisiyi, lati gbọ́ ohun gbogbo ti a palaṣẹ fun ọ lati ọdọ Ọlọrun wá.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:33 ni o tọ