Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Iṣe Apo 10:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Ẹnyin mọ̀ bi o ti jẹ ẽwọ̀ fun ẹniti iṣe Ju, lati ba ẹniti iṣe ara ilẹ miran kẹgbẹ, tabi lati tọ̀ ọ wá; ṣugbọn Ọlọrun ti fihàn mi pe, ki emi ki o máṣe pè ẹnikẹni li ẽwọ̀ tabi alaimọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:28 ni o tọ