Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tim 6:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o si ni oluwa onigbagbọ́, ki nwọn máṣe gàn wọn nitori arakunrin ni nwọn; ṣugbọn ki nwọn tubọ mã sìn wọn, nitori awọn ti iṣe alabapin iṣẹ rere wọn jẹ onigbagbọ́ ati olufẹ. Nkan wọnyi ni ki o mã kọ́ni ki o si mã fi gba-ni-niyanju.

Ka pipe ipin 1. Tim 6

Wo 1. Tim 6:2 ni o tọ