Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tim 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Máṣe jẹ ki ẹnikẹni ki o gàn ewe rẹ; ṣugbọn ki iwọ ki o jẹ apẹrẹ fun awọn ti o gbagbọ́, ninu ọ̀rọ, ninu ìwa hihu, ninu ifẹ, ninu ẹmí, ninu igbagbọ́, ninu ìwa mimọ́.

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:12 ni o tọ