Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tim 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi mo ba pẹ, ki iwọ ki o le mọ̀ bi o ti yẹ fun awọn enia lati mã huwa ninu ile Ọlọrun, ti iṣe ijọ Ọlọrun alãye, ọwọ̀n ati ipilẹ otitọ.

Ka pipe ipin 1. Tim 3

Wo 1. Tim 3:15 ni o tọ