Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tim 1:6-8 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. Lati inu eyiti awọn ẹlomiran ti yapa kuro ti nwọn si ya sapakan si ọrọ asan;

7. Nwọn nfẹ ṣe olukọ ofin; òye ohun ti nwọn nwi kò yé wọn, tabi ti ohun ti nwọn ntẹnumọ́.

8. Ṣugbọn awa mọ̀ pe ofin dara, bi enia ba lò o bi ã ti ilo ofin;

Ka pipe ipin 1. Tim 1