Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tes 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn ba nwipe, alafia ati ailewu; nigbana ni iparun ojijì yio de sori wọn gẹgẹ bi irọbi lori obinrin ti o lóyun; nwọn kì yio si le sálà.

Ka pipe ipin 1. Tes 5

Wo 1. Tes 5:3 ni o tọ