Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tes 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Oluwa tikararẹ̀ yio sọkalẹ lati ọrun wá ti on ti ariwo, pẹlu ohùn olori awọn angẹli, ati pẹlu ipè Ọlọrun; awọn okú ninu Kristi ni yio si kọ́ jinde:

Ka pipe ipin 1. Tes 4

Wo 1. Tes 4:16 ni o tọ