Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tes 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kọ̀ fun wa lati sọ̀rọ fun awọn Keferi ki nwọn ki o le là, lati mã sọ ẹ̀ṣẹ wọn di kikun nigbagbogbo: ṣugbọn ibinu de bá wọn titi de opin.

Ka pipe ipin 1. Tes 2

Wo 1. Tes 2:16 ni o tọ