Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun ore-ọfẹ gbogbo, ti o ti pè nyin sinu ogo rẹ̀ ti kò nipẹkun ninu Kristi Jesu, nigbati ẹnyin ba ti jìya diẹ, On tikarãrẹ, yio si ṣe nyin li aṣepé, yio fi ẹsẹ nyin mulẹ, yio fun nyin li agbara, yio fi idi nyin kalẹ.

Ka pipe ipin 1. Pet 5

Wo 1. Pet 5:10 ni o tọ