Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ gẹgẹ ẹnyin ọkọ, ẹ mã fi oye bá awọn aya nyin gbé, ẹ mã fi ọla fun aya, bi ohun èlo ti kò lagbara, ati pẹlu bi ajumọ-jogun ore-ọfẹ ìye; ki adura nyin ki o má bã ni ìdena.

Ka pipe ipin 1. Pet 3

Wo 1. Pet 3:7 ni o tọ