Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 3:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. BẸ̃ gẹgẹ, ẹnyin aya, ẹ mã tẹriba fun awọn ọkọ nyin; pe, bi ẹnikẹni bá tilẹ nṣe aigbọran si ọ̀rọ na, ki a lè jere wọn li aisọrọ nipa ìwa awọn aya wọn,

2. Nigbati nwọn ba nwò ìwa rere ti on ti ẹ̀ru nyin:

Ka pipe ipin 1. Pet 3