Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 2:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti on tikararẹ̀ fi ara rẹ̀ rù ẹ̀ṣẹ wa lori igi, pe ki awa ki o le di okú si ẹ̀ṣẹ ki a si di ãye si ododo: nipa ìnà ẹniti a mu nyin larada.

Ka pipe ipin 1. Pet 2

Wo 1. Pet 2:24 ni o tọ