Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tabi fun awọn bãlẹ, bi fun awọn ti a rán lati ọdọ rẹ̀ fun igbẹsan lara awọn ti nṣe buburu, ati fun iyìn awọn ti nṣe rere.

Ka pipe ipin 1. Pet 2

Wo 1. Pet 2:14 ni o tọ