Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ìwa nyin larin awọn Keferi kí o dara; pe, bi nwọn ti nsọ̀rọ nyin bi oluṣe buburu, nipa iṣẹ rere nyin, ti nwọn o mã kiyesi, ki nwọn ki o le mã yìn Ọlọrun logo li ọjọ ìbẹwo.

Ka pipe ipin 1. Pet 2

Wo 1. Pet 2:12 ni o tọ