Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu eyiti ẹnyin nyọ̀ pipọ, bi o tilẹ ṣe pe nisisiyi fun igba diẹ, niwọnbi o ti yẹ, a ti fi ọ̀pọlọpọ idanwo bà nyin ninu jẹ:

Ka pipe ipin 1. Pet 1

Wo 1. Pet 1:6 ni o tọ