Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Pet 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹniti a fihàn fun, pe kì iṣe fun awọn tikarawọn, bikoṣe fun awa ni nwọn ṣe iranṣẹ ohun wọnni, ti a ròhin fun nyin nisisiyi, lati ọdọ awọn ti o ti nwãsu ihinrere fun nyin pẹlu Ẹmí Mimọ́ ti a rán lati ọrun wá; ohun ti awọn angẹli nfẹ lati wò.

Ka pipe ipin 1. Pet 1

Wo 1. Pet 1:12 ni o tọ