Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 9:3-5 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Èsi mi fun awọn ti nwadi mi li eyi:

4. Awa kò ha li agbara lati mã jẹ ati lati mã mu?

5. Awa kò ha li agbara lati mã mu aya ti iṣe arabinrin kiri, gẹgẹ bi awọn Aposteli miran, ati bi awọn arakunrin Oluwa, ati Kefa?

Ka pipe ipin 1. Kor 9