Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn fun awa Ọlọrun kan ni mbẹ, Baba, lọwọ ẹniti ohun gbogbo ti wá, ati ti ẹniti gbogbo wa iṣe; ati Oluwa kanṣoṣo Jesu Kristi, nipasẹ ẹniti ohun gbogbo wà, ati awa nipasẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Kor 8

Wo 1. Kor 8:6 ni o tọ